Baba Suwe ti jade laye o Akinpelu Johnson November 24, 2021 0 Lọsan an, yii niroyin gba igboro pe gbajumọ adẹrin pa oṣonu nni, Alaaji Babatunde Omidina, tọpọ awọn mọ si Baba Suwe, jade laye.Ọmọ rẹ, obin... Read more »
Baba Suwe ti jade laye o Akinpelu Johnson November 22, 2021 0 Lọsan an, yii niroyin gba igboro pe gbajumọ adẹrin pa oṣonu nni, Alaaji Babatunde Omidina, tọpọ awọn mọ si Baba Suwe, jade laye.Ọmọ rẹ, obin... Read more »
Lalude fẹẹ ṣayẹyẹ aadọta ọdun to bẹrẹ itage Akinpelu Johnson November 11, 2021 0 Gbajumọ oṣere onitiata nni, Alaaji Fatai Adetayọ, tọpọ mọ si Fatai Oodua, tawọn kan tun pe ni Lalude, fẹẹ ṣayẹyẹ aadọta ọdun, to bẹrẹ iṣẹ ti... Read more »
Bi ala lọrọ iku Tobacco onifuji jẹ fawọn eeyan Akinpelu Johnson February 18, 2021 0 Beeyan ba de adugbo Ijeun Titun, nibi ti gbajumọ oṣere onifuji nni, to jade laye lana an, Alaaji Taofeek Adeyinka, tọpọ awọn ololufẹ ẹ mọ... Read more »
Ẹlẹṣọ, Mista Latin atawọn agba oṣere tiata pejupesẹ nibi ayẹyẹ adura ọjọ mẹjọ Baba Lẹgba l`Abẹokuta Akinpelu Johnson September 14, 2020 0 Gbogbo awọn to wa nibi ayẹyẹ ọjọ mẹjọ Alaaji Yekinni Oyedele tọpọ mọ si Baba Lẹgba lo ya lẹnu nigba ti aarẹ ẹgbẹ oṣere tiata ANTP, Ọgbẹni ... Read more »
Wọn ti sin oku Baba Lẹgba agba oṣere onitiata Akinpelu Johnson September 08, 2020 0 Ni irọlẹ ọjọ Aje, Monde, ana, ni wọn si agba oṣere onitiata nni, Alaaji Kaṣimawo Yẹkinni Oyedele, tọpọ awọn ololufẹ ẹ mọ si Baba Lẹgba, ... Read more »
Ọpẹ o; Ẹniọla Ṣodiya sọrọsọrọ ori redio Rockcity moribọ lọwọ arun koronafairọọsi. Akinpelu Johnson July 16, 2020 0 Lọsẹ meji sẹyin la gbe iroyin kan jade nipa sọrọsọrọ ori redio nni Ẹniọla Anikẹ Ṣodiya tawọn oloolufẹ ẹ mọ si Iyalode pedepede pe o ni... Read more »
Wọn ti sin oku OgunMajek, ọga onitiata Akinpelu Johnson June 26, 2020 0 Lọjọbọ, Tọsidee, ana ni wọn sin oku agba oṣere onitiata nni, Alaaji Gbọlagade Akinpẹlu, tọpọ mọ si OgunMajek, ni ile wọn to wa ni ... Read more »
Ṣẹfiu Alao, Ere Asalatu ati Leke Iyanda ṣe akanṣe ere fun Landoma fayẹyẹ ọjọọbi ẹ Akinpelu Johnson June 21, 2020 0 Lati aarọ yii ni oriṣiriṣi orin ọkan-ọ-jọkan ti n waye lati ba Gomina ẹgbẹ apapọ olorin nipinlẹ Ogun, Alaaji Saheed Akangbe Bọlọmọpe t... Read more »