Baba Suwe ti jade laye o - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Wednesday 24 November 2021

Baba Suwe ti jade laye o





Lọsan an, yii niroyin gba igboro pe gbajumọ adẹrin pa oṣonu nni, Alaaji Babatunde Omidina, tọpọ awọn mọ si Baba Suwe, jade laye.Ọmọ rẹ, obinrin Adesọji Omidina lo sọrọ naa fawọn oniroyin.

Lẹyin ọdun mẹwaa tawọn ajọ to n gbogun ti oogun oloro nilẹ wa, iyẹn NDLEA mu u satimọle pe o gbe oogun oloro.

Lọdun 2019 ni wọn gbe e lọ si ileewosan LUTH, fun itọju, ṣugbọn aisan naa ko ti fi i silẹ ranpẹ ni.

Awọn kan sọ pe latigba ti ajọ NDLEA ti mu ọkunrin alawada onitiata naa ni ko til gba mọ.

Ẹni ọdun mẹtadinlaaadọrin ni Baba Suwe ko too jade laye. Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ.

No comments:

Post a Comment

Pages