Ojulowo ọmọ bibi Yoruba ni wón fi n joye Ọbalẹfun ti wọn fi Gbadebọ jẹ - Ijọ Oloriṣa Parapọ
Akinpelu Johnson
May 03, 2025
0
Ọrọ tun ti foju han pe ojulowo ọmọ bibi ilẹ Yoruna ni oludije gomina labẹ ẹgbẹ oṣelu Labour, nipinlẹ Eko, Gbadebọ Rhodes-Vivour, nigba ti wọ...
Read more »