Ṣọọṣi Genesis fẹẹ ṣe isinaṣa lẹ atunṣe ni ipari oṣu yii - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Friday 15 March 2024

Ṣọọṣi Genesis fẹẹ ṣe isinaṣa lẹ atunṣe ni ipari oṣu yii



Gbogbo eto lo ti to lati ileeṣẹ iranṣẹ Genesis Global city, fun isin aṣalẹ atunṣe iyẹn Restoration night,ti yoo waye lọjọ kọkanlelọgbọn oṣu yii ninu ijọ naa.

Gẹgẹ bi atẹjade to tẹ wa lọwọ lati gbọ pe aago mẹjọ alẹ ni eto ọhun yoo bẹrẹ nibi tawọn olorin ẹmi ọlọkan-ọ-jọkan yoo ti pitu ọwọ wọn.

Lara wọn ni Dare Oxygen, Moji Genesis, Solomon Mayọwa atawọn mii-ii bẹẹ ni Wolii Isreal Ogundipẹ tọpọ mọ si Genesis yoo tun rọjo adura le awọn eeyan lori lọjọ naa.

No comments:

Post a Comment

Pages