Ororo adura Genesis Perfume ti jade o - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Thursday 14 March 2024

Ororo adura Genesis Perfume ti jade oBo tilẹ jẹ pe o tipẹ tawọn kan ti n beeere pe igbawo ni ororo adura ti ojiṣẹ Ọlọrun nni Wolii Isreal Ọladele Ogundipẹ tọpọ mọ si Genesis fẹẹ jade?.

Ṣugbọn ni bayii, idunnu ni lati sọ fun yin pe ororo adura naa ti jade. Fun gbogbo ọkan to n fẹ ibukun, aanu,ilọsiwaju, ọkọ rere paapaa, fun ẹni ti ọna ẹ ko la,ororo adura ti wọn pe ni Genesis Perfume ki ẹ lo. 

Fun alaye kikun lori ororo adura ọhun ẹ le pe sori nọmba yii 0803 579 2122

No comments:

Post a Comment

Pages