Wolii Ogundipe ki Tinubu ku oriire gege bi aare tuntun - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Wednesday 1 March 2023

Wolii Ogundipe ki Tinubu ku oriire gege bi aare tuntun
Wolii Israel Oladele Ogundipe, topo mo si Genesis ti ijo Genesis Global ti ki Asiwaju Bola Ahmed Tinubu ku oriire fun bo se jawe olubori gege bi aare tuntun lorileede yii.

Ninu atejade ti ojise Olorun naa fi sita lo ti so pe Olorun ti mu ero e se ninu eyi to ti wi pe ko si eda kan to le to le yi ipinnu e pada, ohun to ba ti se o ti se niyen..

O wa so pe oun nireti pe Olorun yoo fun ni okun ati agbara lati sakoso orileede yii lona to to ati eyi to ye, ti igba e yoo si ro gbogbo mutumuwa.

Bee ni Genesis tun gba gbogbo awon oloselu yooku nimoran lati sa fun nnkan to ba le da wahala sile.

A o ranti pe lojo Satide Abameta to kọja yii ni won dibo aare orileede, ti won si kede Tinubu gege bi eni to jawe olubori mojumo onii.
 No comments:

Post a Comment

Pages