Seneto Adeola fi emi imoore han sawon eeyan Ogun West - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Sunday 26 February 2023

Seneto Adeola fi emi imoore han sawon eeyan Ogun WestSeneto Solomon Olalekan Adeola, olujawe olubori ninu ibo to waye gege bi asofin agba fun ekun Ogun West, ti dupe lowo awon eeyan naa lori bi won se dibo yan an wole naa.

Ninu atejade ti Oloye Kayode Odunaro, to je alakoso agba fun eto iroyin okunrin naa fi sita ni ale yii ni Yayi tun ti mu dawon eeyan e loju pe gbogbo ileri oun lati mu awon akanse ise idagbasoke ba awon agbegbe naa ni yoo di mouse.

O fikun oro e pe gbogbo woodu mokandinlogota to wa ni Ogun West loun ti de toun si ti mo awon ipenija ti won koju nibe.

O ni  bo tile je pe opo awon ipenija naa loun ti n wa ona abayori si ko to di pe won fi Ibo won gbe oun wole ana yii.

Bee lo tun dupe lowo won fun igbagbo ti won ni ninu oun ti won fi dibo aare won fun Asiwaju Bola Ahmed Tinubu atawon oludije yooku naa

Lale yii ni won kede Seneto Adeola ti Inu egbe oselu APC, gege bi eni to biri ninu Ibo asofin agba fun ekun Ogun West nigba to fidi Oloye Vanity Dada Obanibasiri tinu egbe oselu PDP janle patapata.

Ojogbon Olusegun Oluseye  Onabanjo, tileewe imo ogbin FUNAB, ni Abeokuta lo kede Seneto Adeola ni gbongan Oronna Townhall, Ilaro.

A o ranti pe fun igba marun un otooto bi okunrin yii ti jawe olubori to to soju ipinle Eko nile igbimo asofin kekere to fi de agba.No comments:

Post a Comment

Pages