Onarebu Florence Funlola Akinrinde topo mo si FFA, to je oludije asoju-sofin fun ekun Ifo/ Ewekoro, labe egbe oselu ADC, ti so pe ko si ooto oro ninu aheso kan pe oun ti darapo mo APC.
Ninu atejade ti Onarebu Olumide Onabajo fi sita lo ni obinrin naa soro yii lakooko to n ba awon oniroyin soro, o so pe ko si ninu ipinnu oun rara lati fi egbe to wa naa sile
O ni Iyalenu lo je fun oun pe awon kan gbe aheso kaakiri. O ni loooto ni oludije gomina kan ranse pe oun lati wa darapo mo won lati jawe olubori ninu Ibo to n bo, amo ti oun ko da won lohun.
O ni tokantokan loun fi wa ninu egbe oselu ADC pelu erongba egbe naa lati se atunse lori awon nnkan ti ijoba to wa lode yii ti baje.
FFF waa so pe Iyalenu lo je nigba toun ri lori ikanni oselu kan pe oun gbero lati fi egbe ADC sile, o ala ti ko le se ni.
.
Obinrin naa wa so pe ki won je kawon to n paro maa se niso ko le tu iru kankan lara oun.
Bee lo ro awon omo egbe oselu ADC lati ma se gba aheso to jinna si ooto laaye ki won koju mo bi won yoo se jawe olubori Ibo gomina ti yoo waye ni Satide ose yii.
No comments:
Post a Comment