Tinubu jawe olubori ni wọọdu Ọbasanjọ, ṣe ni Obi lulẹ - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Saturday 25 February 2023

Tinubu jawe olubori ni wọọdu Ọbasanjọ, ṣe ni Obi lulẹ 

Nnkan ko sẹnure fun abajade idibo wọọdu ti Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti dibo aarẹ, iyẹn ni wọọdu kọkanla, ẹkun kẹfa, ẹka kejilelogun, ni Abẹokuta North,nigba ti Aṣiwaju Bọla Ahmed Tinubu, ti ẹgbẹ oṣelu APC na Peter Obi, ẹgbẹ oṣelu Labour, ẹni ti aarẹ ana polongo fun fidi rẹmi.

 

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, ibo mẹrindinlọgọta ni Tinubu ni nibẹ, nigba ti Peter Obi ni mẹsan-an, ADC ni ibo mẹjọ, Atiku Abubakar ni meje, ibo mẹwaa ni wọn wọgile nibẹ. Fun ibo sẹnetọ PDP ni mọkanlelọgbọn, APC ni mẹtadinlogoji nigba Labour ni ẹyọ kan ṣoṣo.

No comments:

Post a Comment

Pages