Gbogbo eto lo ti to fun gbajumo onifuji nni Alaaji Abass Akande Obesere lati fi ere da awon ololoolufe e lola, lojo Abameta, Satide, ose yii ni Manchester.
Ninu fonran fidio ti okunrin naa se to fi pe awon eeyan e lo ti so pe gongo yoo so lojo naa nigba to ba n fi orin, ijo ati ilu DA awon ololoolufe e to wa lohun laraya.
Gege bo se wi, aago mejo ale lo so pe ere naa yoo bere ati pe Dubai Entertainment lo sagbateru ere ojo naa.
O ti wa seleri pe gbogbo igbadun ni yoo wa lojo naa nitori oun ti gbe de felifeli
No comments:
Post a Comment