Mo setan lati mu opo idagbasoke ise akanse wo Ogun West- Seneto Adeola - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 21 February 2023

Mo setan lati mu opo idagbasoke ise akanse wo Ogun West- Seneto Adeola
Seneto Solomon Adeola, to n dije fun ipo Seneto labe egbe oselu APC, ninu Ibo to n bo lojo Satide, Abameta, yii tun ti mu day awon eeyan Ogun West, loju pe opo ise akanse to le mu idagbasoke ba awon eeyan naa loun yoo mu ba won, bi won ba le dibo yan oun wole.

Oludije naa soro yii lakooko to n se eto ironilagbara fáwọn egberun le irinwo ati irinwo le marundinlaadota,ninu eyi tawon igba abarapa wa ninu je anfaani ninu e. Eyi to waye niluu Ilaro.Lara awon to tun je anfaani  ninu eto naa ni awon alabo ara ti Seneto fun ni keke elese meta, gaasi,ohun elo iserun fáwọn obinrin, atawon mii in bee naa ni won tun fun won egberun lona ogorin lati Bere okoowo won.

O tun fikun oro e pe egberun meeedogun awon eeyan ni won tun je anfaani okoowo ati owo latigba to ti bere ironilagbara ni Ogun West, eyi to so pe opo lo ti okan tabi meji se ninu igbe aye won.

Eni topo eeyan tun mo si Yayi tun salaye siwaju pe idi tawon se gbe eto ironilagbara yii kale ni lati fi mu ireti awon eeyan pada bo sipo, paapaa julo lori ipenija ti won koju lori eto oro aje kaakiri orileede yii.

O so pe ko siyemeji  nibe pe opo awon ti won kose atawon ti won to lagbara mi orisi ona ni yoo mu ayipada rere ba igbesi aye won lori idagbasoke oro aje awujo.

O waa pari oro e pe eto naa ki i se asemo foun ati pe nnkan toun ni lokan lati maa se looorekoore. O wa ran won leti lati fi kaadi idibo won dibo foun gege bi asofin agba fun ekun naa atawon oludije yooku ninu egbe APC.

"

No comments:

Post a Comment

Pages