Genesis ni kawon omo ijo si da owo idamewa ati ore duro fun igba die - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Sunday 5 February 2023

Genesis ni kawon omo ijo si da owo idamewa ati ore duro fun igba die




Ara tuntun ni Wolii ijo Genesis Global iyen Wolii Isreal Oladele Ogundipe tun gbe wonu ijo nigba to pase pe ki won si da owo idamewa ati ore, ti won maa n gba lakooko isin duro na.

Ojise Olorun gbe igbese naa nitori isoro owo naira tawon omo orileede you n koju lati bi ose meji seyin.

O soro yii lakooko to n waasu, o ni ti isoro yii ba yanju patapata ni ki won to pada maa da awon owo yii. O so pe awon ijo Olorun naa mo nnkan tawon eeyan Ile yii fojoojumo koju, ko si tun ye ki won da si.

Ogundipe so pe" Ile ni ijo Olorun je fun onikaluku,o si gbodo je ibi ti yoo mu itelorun wa,ki i se ibi to ye ki a tun maa fara ni ara wa.

Won ti wa gba awon omo ijo lamoran lati gba igbese naa,ki won si dupe low oluso agutan naa lori igbese yii titi ti oro aje yoo fi pada bo sipo 

No comments:

Post a Comment

Pages