Egbe oniroyin NUJ tipinle Ogun sedaro Henry Ojoye, to jade laye - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday, 27 December 2022

Egbe oniroyin NUJ tipinle Ogun sedaro Henry Ojoye, to jade laye



Egbe oniroyin NUJ, tipinle Ogun, ti kede oku Ogbeni Henry Ojoye, okan pataki ninu omo egbe naa. 

Ninu atejade ti Bunmi Adigun, akowe egbe naa fi sita lonii, lo ti so pe edun okan lo je fawon pe awon padanu okan lara omo egbe naa. 

Gege bo se wi, ojo Aje, Monde, ana lo so pe okunrin naa jade laye niluu Sagamu. O so pe iyalenu niku e yii je fawon nitori opo awon akegbe e ni won si ri i ni iwe iroyin lana-an, ko to di pe o mu irinajo e pon lo si Sagamu. Ko to di pe won kede oku e lale ojo naa.

Akowe egbe awon oniroyin waa sapejuwe oloogbe naa gege bi akikanju to duro ti egbe nigba ti nnkan le, bee lo ni o seleri atileyin fawon to sese gba akoso. 


Ojoye lo je oga agba fun ileese iwe iroyin
 The Digest Magazine. Odun mejilelogota lo so pe o lo laye. Pelu adura pe ki Olorun forunke, ki o si te si afefe rere, 



No comments:

Post a Comment

Pages