Otegbeye ki Asofin Odebiyi ku oriire oye CON to gba - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Sunday 9 October 2022

Otegbeye ki Asofin Odebiyi ku oriire oye CON to gba


Ondupo gomina labe egbe oselu ADC nipinle Ogun, Agbejoro Biyi Otegbeye, ti ranse ikinni ku oriire si Asofin Tolu Odebiyi, to n soju ekun Ogun West, nile igbimo asofin niluu Abuja, fun ti oye CON, ti won fi da lola.

Ninu atejade ti iko iroyin BOT, fi sits lonii , ni Otegbeye ti ba Asofin naa yo fun oye to Aare Muhammadu Buhari, GCFR, fi da a lola.

O sapuwe ami eye naa gege bi eyi to to si Asofin nitori awon idagbasoke to to mu ba agbegbe to ti wa ati bo se fajin fawon eeyan lati sin won.

Otegbeye salaye siwaju pe " Ko ya mi lenu mi pe won fun  Seneto Odebiyi lami eye nla, nitori o mu ori wa wu to si fi ara e han gege bi ojulowo omo bibi Yewa Awori, ninu ka so nipa asoju rere, okan lọ je nile igbimo asofin niluu Abuja.


Bee lọ tun sapejuwe ami eye naa gege bi eyi ti ko se fowo to seyin, eyi lọ muu ranti Baba Asofin naa, Seneto Jonathan Odebiyi , toun naa ti figba kan je asofin labe egbe oselu UPN.

Otegbeye waa mu da awon eeyan loju pe oun nigbagbo pe ipinle Ogun yoo tun pese awon asoju rere ti egbe oselu ADC ba wole fun ipo gomina lodun 2023.


No comments:

Post a Comment

Pages