Awon eeyan ki Otegbeye ku oriire ayeye ogbon odun to segbeyawo - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Monday 10 October 2022

Awon eeyan ki Otegbeye ku oriire ayeye ogbon odun to segbeyawoLatigba tile ti mo lonii, lawon eeyan jakanjakan niluu ti n ba oludije gomina labe egbe oselu ADC nipinle Ogun, Agbejoro Biyi Otegbeye, sajoyo fun ayeye ogbon odun ti won segbeyawo.

Bee lawon eeyan tun fi adura ran okunrin yii ati iyawo e, Dokita  Comfort Otegbeye, lowo pe ki Olorun oba tubo fi ife to fi so won po latile, tesiwaju, ki aye ma se ja okun ife naa.

Ohun to je ki idunnu naa tubo po si ni pe ola tun ni ayeye ojoobi oludije yii, eyi ti won so pe won kan fee fi dupe lowo Olorun.

Adura wa ni pe ki Olorun tubo ro igbeyawo naa lagbara, kawon mejeeji tubo gun ni emi.

 

No comments:

Post a Comment

Pages