Nitori Onarebu Adiijat:Awon eeyan Akute dupe lowo Dapo Abidun - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Wednesday 21 September 2022

Nitori Onarebu Adiijat:Awon eeyan Akute dupe lowo Dapo AbidunEgbe kan ta a mo si Akute Concerned Citizens, to wa ni Akute nijoba ibile Ifo, nipinle Ogun, ti fi emi imoore won han si Gomina Dapo Abidun lori bi won se Onarebu Adiijat Adeleye-Oladapo, gege bi komisanna for asa ati irinajo afe nipinle naa.
Won itan rere ni Gomina naa fi sile nitori obinrin yii ni komisanna akoko ti won yoo lati agbegbe ekun Ifo keji.

 Fifi emi imoore yii waye lakooko tawon eeyan ohun sabewo lo ki Komisanna naa ni offisi e.

Niigba to n soro loruko egbe yii Onarebu  
 Lekan Soyemi, tun fikun oro e peawon ise akanse imayederu ti Gomina ti se sawon agbegbe won you tun je awon ohun amoriya to si fihan pe asaaju to feran araalu e ni Gomina Dapo Abiodun.

 Bee lọ tun lo akoko naa lati ro Gomina lati tesiwaju ninu awon ise rere to n se kaakiri ipinle  Ogun.
Nigba to n fesi, Onarebu Adiijat dupe pupo lowo eeyan naa bee lọ tun gba won lamoran lati rii pe won gba alaafia laaye lati joba niluu Akute, ki won si fara won han gege bi ojulowo omo agbegbe naa.

Bakan naa lo tun so fun won pe ki gbogbo won wa ni isokan ki won ba tubo le ri mundunmudun ijoba tiwa n tiwa je.

Onarebu Adiijat to tun se ipade po pelu awon asaaju obinrin lawon ijoba ibile gba won lamoran lati satileyin fun Gomina Abiodun fun erongba eleekeji e

No comments:

Post a Comment

Pages