Awon ara Agbado fi oko ranse si Dapo Abiodun lori agbara ojo to gbona mo won lowo - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Thursday 22 September 2022

Awon ara Agbado fi oko ranse si Dapo Abiodun lori agbara ojo to gbona mo won lowo


Latigba tawon eeyan kan niluu Agbado nijoba ibile Ifo, nipinle Ogun, ti gbe bi agbara ojo se ba ona je mo won lowo ni won ti fi oko oro ranse si Gomina Dapo Abiodun.

Gege fidio ti won gbe sori ero ayelujara, o safihan bi ekun omi se gba gbogbo ona titi koja, ti ko si je kawon moto raye koja.

Koda gbogbo awon Ile to wa legbe e ni ekun ohun se lose. Oro ti eni to gbe fidio naa jade n so ni pe ilu Agbado lawon wa yii oo. Gomina Dapo Abiodun, e wo ibi ti e bawon de, e si so pe e n lọ eleekeji, eyin lọ kan.

Opo awon to ri fidio ohun ni won fenu tabuku ijoba to wa lode yii, bo tile je pe awon ko lọ bere ise akanse ona naa, sugbon won ni ko was ye ki Dapo Abiodun pa a ti debi pe ona naa yoo wa baje koja siso.

Awon kan tie so pe nnkan kekere ko nisoro tawon maa n foju ri tawon ba gba ona naa koja, opo moto lọ si ti baje Lori ona naa.

Enikan to ba wa soro so pe oun ko ri si awon irin ti ko nitumo ti Gomina so pe oun rin sawon ona kan nigba to je pe eyi to ye ko mojito, ko se e.

Ni bayii awon to n gbe lagbegbe naa ti so pe emi awon ko de lori ipo ti agbara ojo so Agbado naa da, nitori nnkan mii-in si ko bi ko se omiyale agbara ya soobu.

No comments:

Post a Comment

Pages