Egbe oselu Labour Eko yoo gbe oruko fidie alaga ijoba ibile jade lola - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Wednesday 28 September 2022

Egbe oselu Labour Eko yoo gbe oruko fidie alaga ijoba ibile jade lola



Egbe oselu Labour tipinle Eko, ti kede pe awon yoo gbe oruko awon kiatika alaga ijoba ibile ti won ti yan sits ni ola Ojobo, ojo kokandinlogbon, osu yii, sita.

Gege bi atejade ti Iyaafin Olubunmi Odesanya, to je akowe olupolongo egbe naa fi sita lo tun salaye pe bakan naa loruko awon yooku ti yoo je ki gbongbo egbe ohun tun lo soke lawon ijoba ibile onidagbasoke metadinlogoji to wa nipinle ohun yoo tun jade pelu.

Bee lo tun fi kun oro e pe leyin tawon ba kede tan lola lawon yoo safihan awon eeyan wonyii fun agbaye nibi ipade oniroyin ti yoo waye, eyi ti ko nii ju ojo meje si akoko yii lọ.

Pelu gbogbo eleyii akowe olupolongo so pe o ti fihan gbangba pe egbe oselu Labour duro daadaa nipinle Eko, lati gba akoso ninu ibo to n bo lona

No comments:

Post a Comment

Pages