E gbarukutu ti Toyin Amuzu lati wọle ibo aṣoju-ṣofin niluu Abuja- Ladi Adebutu - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 16 August 2022

E gbarukutu ti Toyin Amuzu lati wọle ibo aṣoju-ṣofin niluu Abuja- Ladi Adebutu

Ọnarebu Ladi Adebutu, oludije fun ipo gomina labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP, nipinlẹ Ogun, ti rọ awọn eeyan agbegbe Abẹokuta South, lati gbarukutu, ki wọn dibo wọn fun Toyin Amuzu, gẹgẹ bi aṣoju-ṣofin fun ẹkun naa nibi ibo to n bọ lọdun 2023.

Ọkunrin naa sọrọ yii nibi ayẹyẹ ṣiṣi kangadẹrọ ti Toyin Amuzu. ṣe fawọn eeyan agbegbe Isalẹ-Igbẹhin, to waye lọjọ Iṣẹgun, Tusidee

. O sọ pe akinkanju to ni erongba rere fawọn eeyan ẹ ni oludije ọhun.

O waa sọ pẹlu idaniloju pe igbe aye idẹrun lawọn eeyan ọhun yoo maa gbe ti oludije labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP, naa ba fi le wọle ninu ibo to n bọ yii. 

Bakan naa lo tun lo akoko yii lati sọ fun gbogbo awọn eeyan ipinlẹ Ogun lapapọ lati dibo gomina wọn fun oun.

O sọ pe kawọn eeyan naa maa jẹ ki APC, tun fi akoko wọn ṣofo fọdun mẹrin mi-in.

 

 


No comments:

Post a Comment

Pages