Ọladẹdinde ọkan lara afurasi ti wọn pa Sọfiat ti gba itusilẹ - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 15 March 2022

Ọladẹdinde ọkan lara afurasi ti wọn pa Sọfiat ti gba itusilẹ


 

Ile-ẹjọ majisireeti to n gbọ ẹjọ awọn ọdọmọde ti wọn pa Sofiat Okeowo, lati fi ṣoogun owo ti paṣẹ pe ki wọn fi Wariz Ọladẹinde, to jẹ ọkan lara wọn silẹ, pe ki o maa lọ sile layọ ati alaafia,

 

Gẹgẹ bi a ṣe gbọ, lọjọ Mọnde, ana, ni Adajọ ile-ẹjọ ọhun Onidajọ I.O Abudu, paṣẹ pe ki wọn lo tu Ọkadẹhinde silẹ gẹgẹ bi amọran to gba lati ọdọ awọn alakoso to n gbọ ọjọ.

 

O ni ki wọn lọọ fi silẹ ni ọgba ẹwọn Ọba, to wa pẹlu awọn akẹgbẹ ẹ tu wọn jọ n jẹjọ ipaniyan.O ni bigba ti wọn ba n fiya jẹ alaiṣẹ lọrọ ẹ ri nitori ko si ẹsun kankan ti wọn ka sii lẹsẹ.

 

Onidajọ Abudu sọ pe oun gbe idajọ oun kalẹ lori iwadii tawọn ọlọpaa ti ṣe, eyi to jẹ ki wọn mọ pe ko mọwọ ko mẹsẹ lori gbogbo awọn nnkan to ṣẹlẹ ọhun. Arinfẹsẹsi lo fẹẹ ko ba a.

 

A o ranti pe ninu oṣu kin-in-ni ọdun yii, ni wọn fẹsun kan awọn ọdọ mẹrin,

Mustakeem Balogun ati Sọliu Majẹkodunmi, ti wọn jẹ ọrẹkunrin Sọfiat pẹlu Ọladeinde ati Abdulgafar Lukman.pe wọn ge ori Ṣọfiat, wọn si gbe ka ina lati fi setutu laduugbo Oke-Aregba, niluu Abẹokuta.


Ni bayii, Addajọ ti wọn sun igbẹjọ siwaju si ọjọ kejilelogunm oṣu kẹrin, ọdun yii nibi tawọn mẹta yooku yoo ti maa ba ẹjọ naa l


1 comment:

  1. Fund bonuses might include wagering requirements, which set the variety of times players should guess the bonus quantity earlier than making withdrawals. Some on-line casinos have excessive wagering requirements, while others don’t have any in any respect. As you likely seen above, welcome bonuses differ in worth 카지노사이트 and may or might not include wagering requirements.

    ReplyDelete

Pages