Ọjọgbọn Kẹhinde Akinọla fẹẹ ṣe idanilẹkọọ ni ọl lọgba ileewe FUNAB - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 7 December 2021

Ọjọgbọn Kẹhinde Akinọla fẹẹ ṣe idanilẹkọọ ni ọl lọgba ileewe FUNAB


Gbogbo eto lo ti to fun ti idanilẹkọọ kọkandinlaadọrin, ti Ọjọgbọn Akinọla Kẹhinde Akinọla ti ẹka kẹmisiri lọgba ileewe giga yunifasiti imọ ọgbin, iyẹn Federal University of  Agriculture, Abẹokuta. FUNAB.

Gẹgẹ bi atẹjade kan ti Ọgbẹni Kọla Adepọju, to jẹ alukoro fọgba ileewe ọhun fi sita, aago meji ọsan lo sọ pe eto naa yoo bẹrẹ ni  gbọngan Oluwafẹmi Balogun Ceremonial Building, to wa ninu ọgba naa.

Olugbalejo pataki ọjọ naa ni Ọjọgbọn Felix Kọlawọle, ọga agba ileewe ọhun. Bẹẹ lawọn ọjọgbọn ni oriṣiriṣi ẹka nileewe naa yoo tun wa nijokoo fun idanilẹkọọ yii

No comments:

Post a Comment

Pages