Nibi ipade ẹgbẹ naa to waye lawọn oloye ẹgbẹ naa lapapọ ti yan awọn igbimọ fidihẹ tuntun naa. Awọn yooku ti wọn tun yan ni Adesina Abraham, NRM, gẹgẹ bi akọwe, Adebisi Adewale, ACCORD, oun ni akapo.
Awọn yooku ni Ayọ Jinadu, lati ẹgb SDP, oun ni alukoro ẹgbẹ, Gbenga Ṣobọwale ti ẹgbẹ SDP,akọwe olupolongo, Kẹhinde Ọyatayọ, APM, akọwe iṣuna ati Adeniyi Fẹmi lati APC, si wa fawọn ọdọ.
Ninu ọrọ alaga tuntun naa, Ọginni, seleri pe ko nii si ojuṣaaju ninu ijọba oun ati pe awọn yoo maa ko ipa pataki.
No comments:
Post a Comment