Ṣẹgun Ṣowunmi, agbẹnusọ fun igbakeji aare orilẹ-ede yi tẹ̀lẹ́ Atiku Abubakar, labẹ ẹgbẹ oṣelu PDP, ninu ipolongo ibo to waye lọdun 2019 ti ṣapejuwe iku to pa Buruji Kashamu, ti ọpọ mọ si Buruji Kaṣhamu gẹgẹ bi ẹkọ nla fawọn oloṣelu Naijiria.
O sọrọ yii nigba to n ba oniroyin sọrọ fun ti ibanikẹdunu agba oloṣelu wa la ọhun. O ni kani wọn sọ fun un pe ko yanju gbogbo aawọ to wa laarin oun atawọn oloṣelu ẹgbẹ ẹ pe akoko ẹ tiu fẹẹ too, o le mab kọbiaraodiyan si iO ni ọrọ to maawi n sọ ni pe “Ofo ọjọ keji ọja ṣe bi tí eeyan ba ti ku o ti tan niyẹn” lo faa to fi ma n huwa bo ṣe n huu, to si ma n ṣe nnkan to ba fẹ ṣe doju ami lai bẹru eeyan kankan, to si tun ma n fawọn eeyan lowo.
Ṣẹgun Ṣowumi sọ pe' Mo ranti ọjọ taa jọ lọ síbi kan niluu Abuja, ṣe lo n fun awọn eeyan lowo lati ita titi ti a fi de ọdọ ẹni ti a n lọ.Nigba ta tun debẹ lọjọ keji lo ba tun n fun wọn lowo debi pe ikan ninu awọn ti wọn gbowo tẹlẹ ni ọga, ẹ ti funmi lowo lana.”oni ígba yẹn nkọ ṣe kiiṣe ojoojumọ lo yẹ keeyan ma jẹun ni”.
Mo sọ fun lọjọ yen pe owo to n na ti pọju, oni mo n nawo toriwipe won ti gbọ nipa mi tẹlẹ pe
Ko si oloṣelu kankan to le nawo tabi lọmọlẹyin bii Buruji, tori konawo nitoripe o n wapo”nnkan to faja wa ri níyen nigba to kan tiẹ ma n nawo ni gbogbo ibi tabalọ mo wa beere lowo ẹ lọjọyẹn pe ọmọọba ki lẹ n wa tẹ ṣe n nawo bayi, o ni mi o wa nnkan kan jupe kawọn eeyan le ma ri i pe ootọ ni nnkan ti wọn n gbọ nipami pe mo ma n fawọn eeyan lowo; mo wa sọ fun un lọjọyẹn pe oṣelu koribẹ awọn to ba ti wa nipo kan ri ninu oṣelu nikan lẹnu wọn ma n tọrọ nibi oṣelu kiiṣe olowo tabi ẹni to n nawo yàfùnyàfùn, adara kẹlọ dipo kan mu, ọrọ ti mo sọ yẹn lo jẹ ko lọ si senetọ labuja.
Yatọ si awọn oloṣelu to ma mọ iku ẹ lara awọn to wa ladugbo ẹ̀ nijẹbu igbo na ma mọ lara ju tori ọjọ gbogbo bi ọdun nile Buruji boṣe nífẹ awọn mọlẹbiẹ gan lo nifẹ awọn mẹkunnu.
Nnkan to ṣẹlẹ nigba ti eto idibo 2015 n bọ ti jẹ ko dami loju pe ko si oloṣelu to le nawo bi Buruji tori ko bẹru lati na gbogbo owo to wa lapo lṣuna ẹ, kosi owo mọ lọjọyen o wa fẹ ta awọn nnkan ini ẹ kale rowolo, boṣe n bawọn to fẹ ta sọrọ pe oya ẹjẹ ki wọn ra ẹgba iye ti wọn ba fẹ san kíakia, ni mo ba ni ẹgbọn kin lo de tẹ fẹ ta ogun to yẹ kẹ fi silẹ fawọn ọmọ yin nitori oṣelu .oni “Ṣegun gbogbo owo to wa lọwọ mi ti mo rope ama fi bẹrẹ ipolongo ibo ni mo ti na kajọ eleto idibo le fi orukọ wa sinu awọn ti wọn ma díbo fun, asi ti nilo owo bayi idi niyen ti mo ṣe fẹ ta , maṣeyọnu ma ra imi pada”.
Buruji kiiṣe ẹni to tete ngba imoran amọ ti eniyen ba duro lori nnkan to ba n ṣe o ma gba sii lẹnu
Nigbati abẹrẹ ọrọ GNI ni 2015 ko kọkọ gba emi atiwọn fa ọrọ yẹn lati aago mẹjọ alẹ titi di aago mẹrin afẹmọju ki wọn to ṣẹṣẹ gba pe kalo fun gomina wọn wa bimi pe Ṣẹgun ṣe GNI ko ni da mi ,lẹyin iyen ni wọn ṣẹṣẹ bẹrẹ iṣẹ́ pẹlu rẹ de bi wipe wọn ta awọn nnkan ini wọn kale rowo na nigba ipolongo ibo.
Lootọ awọn eeyan kan ko fẹran Kaṣamu,ṣugbọn tẹ ba beere nnkan to dajasilẹ̀ laarin wọn ẹ ma riipe ti wọn ba sọrọ mẹwa awọn ni wọn ma jẹbi mẹjọ nibẹ.
Nnkan to ma n bi Kaṣamu ninu ju ni ki eeyan má tẹ̀lé adehun ti wọn jọ ṣe, oun ko ni yẹ adehun ṣugbọn tẹ ba ti yẹ adehun pẹrẹn ko kọ nnkan to ma ṣẹlẹ ,ọrọ tẹyin kasi kekere yẹn ẹsẹkẹsẹ lo ma sọ di nla to ma si sọ fun awọn agbẹjọro re pe ki wọn gbe ọrọ ọhun lọ si ile ẹjọ ọrọ yẹn ko ni wa ṣe yanju lasiko.
Ko yẹ ki Buruji ba awọn agbaagba ẹgbẹ ja debi to de yen toba tiẹ jare oyẹ ko wa ọna lati pariẹ ni, lootọ tẹ ba beere nnkan to dajasilẹ̀ laarin wọn ẹ ma riipe ti wọn ba sọrọ mẹwa awọn ni wọn ma jẹbi mẹjọ nibẹ gẹgẹ bi moṣe sọ tẹlẹ.
Nnkan to yẹ kawa ọmọde ma ro ti edekoyede ba waye laarín awa ati awọn agbalagba nipe awa ọmọde gan ṣi n bọ nipo agba yẹn lọjọ kan! bo tiẹ jẹ pe iku da ẹmi ẹ legbodo laarin wa kalo ro bayi ni boya ati yanju awọn ija yẹn kọlọjọtode.
Buruji ko beru ẹnikẹni to ba ti dọrọ ija lba jẹ ọmọde tabi agbalagba abayinja doju amin titi nnkan to n fẹ fi ma tẹ lọwọ.
Buruji ko figba kan kan sinmi ẹjọ ti ti to fi ku tẹ ba wo ọpọ ile ejọ lorile-ede Naijiria loni ọpọ ẹjọ ti wọn n ṣe nibẹ lo jẹ pe Buruji lo n tukọ rẹ.ṣugbọn ti Buruji ba ji lọla oṣeeṣe ko ma kabamọ inu ẹ ma dun pe oun ṣe nnkan to wu oun nigba ti oun wa laye ni
No comments:
Post a Comment