Bo tilẹ jẹ pe o
tipẹ ti aisan naa ti wa lara Ọkunrin agba oṣere onitiata nni, Alaaji Gbọlagade
Akinpẹlu, tọpọ awọn eeyan mọ si Ogun Majek, ṣugbọn ni bayii o ti n fẹ iranlọwọ
awọn araalu, nitori bi wọn ṣe ni aisan naa ti gbogbo igba n le si.
Adura si lawọn
ẹbi ẹ fi n ran lọwọ bayii, pe ki Ọlọrun ba wọn dawọle ọkunrin to ti kopa ninu
awọn ere tiata yala ori itage, tẹlifiṣan ati fiimu, o si tun wa lara awọn to n
gbe asa ati ede Yoruba larugẹ.
Nibi ti nnkan de duro bayii, Ogun
Majek nilo iranlọwọ awọn araalu fun itọju to peye. Ẹnikẹni to ba fẹẹ ran baba
yii lọwọ, ẹ fi ohun ti ẹ fẹẹ fun un sinu akaunti yii; 0125019443 Akinpelu
Akeem Abidemi GT bank. .
|
||
No comments:
Post a Comment