Bi nnkan se n lo, bo se n loo yii, ose to n bo ni egbe osere tiata ANTP yoo seto ibo lati yan awon oloye egbe tuntun lapapo, tyi imurasile e si ti n loo lowo.
Gege bi Ogbeni Babatunde David Oladehinde topo
mo si Jegi, to je alaga igbimo to seto ibo naa se ba oniroyin wa so laaaro yii,
o ni gbogbo omo egbe lo ti wa ni igbaradi lati yan awon oloye tuntun naa.
O so pe pelu
bi ogo ti n je ti Olorun, Ojoruu, ojo kejilelogun si ojo Eti, Furaidee, ojo
kerinlelogun lawon ti la sile fun eto ibo naa, bo tile je pe won ko tii fee
daruko ibi ti won yoo ti dibo naa nitori abo, sugbon ni awon yoo dibo
Okunrin naa
ni tojo ba fee pe awon yoo so ibi ti awon yoo ti dibo, nnkan to si faa ni awon
idokujo ti won maa n koju bi won ba fee seto iru ibo bayii.
Oladehinde
tun fi kun oro e pe gbogbo awon oludije ti won jee dije ninu ibo naa ni won ti
gba foomu, ti won yoo si daa pada lojoruu, ose yii.Awon meji lo so pe won fee
dije fun ipo aare egbe naa/
Alaga igbimo
naa tun so pe o da oun loju pe Asaolu to je aare egbe naa tele ko tun ni
fee da wahala sile nitori gbogbo nnkan
tawon n se lo ni ofin ninu ati pe oun naa ko nii fe pe ejo ti yoo padanu.
O so pe
akoko Asaolu ti pe lati odun to koja nigba to ti se odun mejo sugbon to ko lati
yan awon ti yoo je kiatika titi ti won yoo fi seto ibo mii in, idi niyii tawon
igbimo agba egbe naa se yan awon fidihe eyi ti Oodua je alaga won.
O ni awon
yii lo seto igbimo ti yoo seto ibo toun je alaga won, o ni awon nigbagbo pe
opin ti de ba gbogbo wahala ti Asaolu n ba egbe fa lati odun 1998.
O wa seleri
pe didun ni osan yoo so fun ibo egbe naa to n bo nitori awon ko njj figba kan
bokan ninu.
No comments:
Post a Comment