Gege bi Oba to feran ohun rere, to
si fee maa n wa nibi ti won ba ti n se nnkan rere, paapaa to tun maa n ba awon ti won n se rere jokoo papo, idi
niyii ti Olu Itori, Oba Fatai Akorede Akamo se wa nibi ti egbe Abeokuta Club ti
gbawon eeyan tuntun wole.
Lara awon ti won sese gba wole gege
bi omo egbe tuntun ni Gomina Dapo Abiodun, tipinle Ogun. Oba Agbodere kin in ni,
naa wa nibe lati wa sayesi fun Gomina to n se ayeye ogorun un ojo lowo.
Oba yii ya foto peluu akowe ijoba nipinle Ogun ati
Onarebu Adijat Adeleye nibi ayeye naa.
No comments:
Post a Comment