Oba Fatai Akorede Akamo, Olu tiluu Itori, ti ba Alake tile Egba, Oba Adedotun Aremu Gbadebo, sajoyo ayeye odun kerindinlogorin ti oba alaye naa dele aye.
Ninu ise to fi ranse si wa lo ti so
pe ojo ana, Satide, Abameta ti Oba naa sojoobi je ojo ayo, nitori pe ojo to
lapeere ninu itan ile Egba pe oba naa sayeye yii lori ile.
O wa gbadura pe ki Oba naa tun se
opo odun laye, ki o si muu gbogbo omo ile Egba lokunrin ati lobinrin de ile
ileri.
Oba Itori wa pari oro e pe’ Inu mi
dun lati ba olori gbogbo ile Egba, Aagbo Aato,!!! Orisa kan soso tegba n sin,Kabiyesi
ku oriire ojoobi e, Igba Odun Odun Kan.
No comments:
Post a Comment