Gbajumo onitiata nni, Olalekan
Olatunji, ti n gbaradi lati sayeye onibeta leekan soso, eyi ti yoo waye lojo
keedogbon, osu yii niluu Abeokuta.
Gege bi a se gbo, lojo naa ni okunrin naa fee sojoobi, bee lo
tun fee se ifilole fiimu tuntun kan to pe akole e MOKOORE, yoo tun lo akoko naa
lati fawon eeyan awujo ni ami eye.
Gbongan Fed Evento Palace, ni Isale
Igbehin, Abeokuta, nipinle Ogun ni ayeye naa yoo ti waye bere ni dede aago
mejila osan.
No comments:
Post a Comment