Gbajumo olorin esin islam nni, Alaaji Abdulkabir Alayande, topo mo si Ere Asalatu lo forin okan-o- jokan da awon eeyan ilu Itori lola nibi ayeye Ode-Oba, eleekerin iru e, to waye ni oja ilu Itori, lojo Aiku, Sannde.
Ayeye to
waye naa lawon eeyan pataki to fi mo awon oba alade, ti fese rajo si orin
okunrin naa, nibi ti oju agbo naa dun de, awon oloolufe okunrin naa ko fee ko
lo mo lojo naa.
Nigba to n
soro nipa olorin ojo naa, Oba Fatai Akorede Akamo dupe lowo e gidi pe o ka oun
atawon eeyan ilu e si fun bo se wa forin da won lola.
Oba naa so
pe nigba tawon igbimo koko pe e o so pe oun yoo gba egberun lona eedegbeta
naira, sugbon iyalenu lo je pe Ere Asalatu ko gba kobo lowo won, to fi wa sere
naa.
O wa sadura
fun un pe ilosiwaju yoo maa deba nibi gbogbo to ba de.
No comments:
Post a Comment