Gege bi ona lati dabobo awon ile to
je ti ile wa Naijiria pelu awon to paala pelu e, ileese asobode iyen kositoomu,
ileese to n ri si wole-wode iyen imigiresanAs part of measures to secure
Nigeria’s land and maritime borders, pelu ajosepo awon ologun atawon olopaa pelu
awon alaabo ilu yooku ti setan lati jo sise po
feto abo odi ilu, eyi ti won pe ni “EX-SWIFT RESPONSE”.
Gege bi a se gbo, ofiisi to n ri si
eto abo lorileede yii Office of the National Security Adviser (ONSA) lo sakoso
eto naa, eyi ti won so pe yoo waye lawin igun mereerin orileede yii.
Iwadii fi ye wa pe eto naa yoo tun
mu igbega ati ajosepo to danmoran wa
pelu imurasile lati safikun idojuko ato abo lawon boda ti yoo si gbogun
ti awon iwa ibaje ati odaran lawujo.
Bee la tun gbo pe eto naa yoo tun
nii se pelu lilo-soke -lo-sodo, awon ohun elo lawon agbegbe ti won yoo ti seto
naa lorileede yii.
Won wa ro awon araalu pe ki won ma
beru tabi sojo, ki won si maa ba ise oojo won lo nitori pataki eto naa ni lati
rii pe alaafia ati abo to peye fun anfaani abo lapopo.
No comments:
Post a Comment