Alaabo ilu siifu tipinle Ogun ti mu dawon
eeyan ipinle naa loju pe awon ti setan feto abo fodun ileya ati leyin e, ki
ohun gbogbo le lo ni irowo-rose
Gege bi atejade ti agbenuso alaabo
ilu naa, Ogbeni Ogbonnaya fi sita loruko oga agba ajo naa, Hammed Abodunrin, lo
ti pase pe ki won ko awon osise won sawon ibi to letoo lakooko odun ileya ati
leyin e.
O salaye pe gbogbo awon osise alaabo
siifu ni won ti pin kaakiri awon ipinle naa atawon ibi gbogbo ti ayeye odun
ileya yoo ti waye ti fi mo awon ile igbafe, awon ibi ti won yoo ti kirun atawon
ibo mii in, ti won si pase pe ki won rii pe abo to peye wa fawon agbegbe ibi ti
won ba wa.
Atejade naa tun salaye pe akoko odun
lawon odaran maa fee n sise ibi won, idi niyii tawon naa fi se wa ni imurasile
lati pese abo to peye, ki won sir ii pea won araalu fi alafia se odun won.
Bee naa nileese siifu difensi tun
fawon nomba foonu kan sita fawon araalu lati pe won ti won ba gbo firi awon
onise ibi tabi awon odaran ti won le fee da ilu ru. Awon nomba naa ni 08033632778/08050726803/08022863415/07067528776..
Hammed Abodunrin wa ki gbogbo awon
musulumi ku imurasile odun ileya naa peu adura pe won yoo se temiin layo ati alaafia
No comments:
Post a Comment