Ki i tuntun mo pe ajo
alaabo lorileede yii iyen Sifu gbe awon oga agba lawon ipinle kan loo si ibomii
in, eyi tawon toro naa kan ti loo bere ise nibi tuntun ti won sese gbe won lo
naa.
Lara awon oga agba naa
ti ise gbe kuro nibi to wa tele ti won gbe wa si ipinle Ogun ni Hammed
Abodunrin. Eni taa gbo pe o ti bere ise loju ese bayii.
Gege bi agbenuso fajo
alaabo naa Dyke Ogbonnaya se wi, lojo Eti, Furaidee, ni nnkan bii aago marun un
ku iseju metalelogoji ni Abodunrin de siluu Abeokuta.
Loju ese lo si ti loo
sabewo mo- mi- in mo o si Alhaji Shuaib Afolabi Salisu, to je olori awon osise
gomina nipinle Ogun, ti onitohun si ki i kaabo pelu ileri pe ajosepo to ti wa laarin
alaabo Sifu ati ijoba ipinle Ogun yoo tubo danmoran.
A o ranti pe Everestus
Obiyo, ni oga agba to wa nibe tele ki ise to gbe loo si Enugu nibi toun naa ti bere ise bayii.
No comments:
Post a Comment