Lonii, ojo Furaide, Jimo,ni ayeye eto isinku Alagba Joseph Olusegun Sonde, to je Baba Alakoso, ijo Kerubu ati Serafu lagbaye yoo waye.
Soosi Kerubu
ati Serafu, Ebenezer Communion ni ayeye isinku naa yoo ti waye ni nnkan bii
aago mesan-an aaro ni isin naa yoo bere, nigba ti won yoo isinku yoo si waye
leyin ti won ba pari isin ni ogba soosi naa. Ko to di pe ayeye weje wemu yoo
waye ni papa isere Muda Lawal, Asero niluu Abeokuta.
Awon ebi Baba Alakoso |
Ojoobo,
Tosidee, ni apapo ijo Kerubu ati Serafu sayeye ikeyin fun Baba Alakoso naa nibi
ayeye aisun onigbagbo to waye nibi ti dagbere fun Baba naa.
Lana an yii
lawon omo ogun to je omo ijo naa ti sayeye lorisirisi fun Baba Alakoso naa.
Alagba Sonde lo jade laye lojo kesan an osu to koja, leyin to lo odun
metadinlaadorun laye.
Alaga igbimo,Onajobi ati Alagba Thomasa |
No comments:
Post a Comment