Awon osise ijoba lati Yewa\Awori
iyen Ogun- West ti fami eye asoju awon osise lati agbegbe naa iyen Ogun-West
Public Servants Forum (OWPSF), da igbakeji gomina nipinle naa, Noimot Salako-
Oyedele lola pelu ileri pe awon yoo satileyin fun ijoba lati le je ki erongba
won se fawon eeyan.
Ayeye yii waye nigba ti Igbakeji
gomina n gba awon eeyan naa, eyi ti Agbejoro Olusegun Olaotan, saaju won lalejo
si offisi e. Nibi to ti gboriyin fawon osise ijoba naa fun bi won se fun-un
lami eye naa, gege bi eni to soju won lati agbegbe won.
Salako wa mu dawon eeyan naa loju pe
asoju rere loun yoo je fun won ati pe gbogbo nnkan ti won soro lee lori loun
yoo sise le lori.
Gege bo se wi, O sapejuwe Gomina Prince
Dapo Abiodun gege bi eni to maa n duro lori oro e, o ni Ogun-West yoo rowomu
daadaa ninu ijoba tawon n lo loo yii.
O wa ni gbogbo igba ti won ba fee ri
ijoba ni aye wa fun won ati pe ijoba setan lati satileyin fun niwongba to je pe
ero okan won ni lati jot un ipinle Ogun se.
Ko
to to akoko yii ni Agbejoro Olusegun Olaotan, to saaju iko naa wa ti ba ijoba
to wa lode yii fun aseyori ti won se lori igbajoba tuntun, pelu idaloju pea won
yoo satileyin fun ijoba naa lati le kese jari.
Ninu oro Alagba Sola Adeyemi, to ti
figba kan je olori awon osise nipinle Ogun, o so pe oun to dara ati idunnu ni
lati ni iru eeyan bii igbakeji gomina laarin won.
Pelu afikun pe gbogbo ija awon ni
lati rii pe awon ipo to ba wa wa kaakiri laigbe sibi kan ju ibikan lo, o ni
awon dupe Olorun fun igbakeji gomina ni oore-ofe lati wa nipo agbara to wa
lonii.
No comments:
Post a Comment