Won ni igbeyawo Kunle Afolayan ti daru patapata - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Sunday 2 June 2019

Won ni igbeyawo Kunle Afolayan ti daru patapata


Kunle Afolayan ati iyawo e, Tolu
 
Aheso lawon eeyan to koko gbo oro naa pe e, bee lawon kan so pe ko le je bee ati pe oku oru ni won fi see sugbon ni bayii, oro naa ti foju han

Gbajumo osere tiata nni, Kunle Afolayan ni won so pe aarin oun ati iyawo e, Tolu ti daru patapata, nibi toro naa de,Tolu ti ko kuro nile toun ati oko e gbe.

Won ni ko mu oro naa ni kekere nitori obinrin yii ti gba looya to fee fi ba oko e, Kunle sejo, Kunle naa si ti so fun adajo pe oun ni ki won ko awon omo to wa laarin awon fun.

Awon to mo bo se n loo laarin awon mejeeji to fi to wa leti so pe won ni owo ati ife ti ko si laarin won mo lo da surutu sile laarin won.

Won ni Tolu to je omo ile Amerika lo n gbo bukaata ile, won ni opo igba ni lo ti fesun kan oko e pe o n yan ale, toro naa si n fojoojumo da ija sile.

Won ni Kunle so fun iyawo e lenu ojo meta yii pe ko je kawon loo se faaji ni Amerika  pelu awon omo won, sugbon ti Tolu so pe Dubai ni ko je kawon lo, o ni owo Dubai loun ni, oro yii lo di wahala nla laarin won, ti Tolu fi loo fowo e ra ile.  
 
Bee ni won tun so pe Tolu naa ko da wa laireni fi nnkan sii labe lo mu ki o sa tele okunrin olowo kan ti won jo n gbe si ara won labe, koda won ni omo jayejaye naa sese ra moto olowo nla fun un ni



No comments:

Post a Comment

Pages