Segun to fipa bomo odun merindinlogun sun so pe ise esu ni - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Sunday 30 June 2019

Segun to fipa bomo odun merindinlogun sun so pe ise esu ni





 Segun Olawoyin, omo ogbon odun, towo awon olopaa iluu Ibafo, nipinle Ogun te lori esun pe o fipa bomo odun merindinlogun sun ti so pe ki won dariji oun ise esu ni,

Lojo Eti, Furaide, ojo kokandinlogbon, osu kefa, lowo te okunrin alailojuti yii, won ni nnkan bi aago kan abo osan nisele naa waye, nigba to loo sile awon omobinrin to baa sun naa, ti won ni ebi kan naa ni won.

Gege bi atejade ti Ogbeni Abimbola Oyeyemi, agbenuso awon olopaa nipinle Ogun se wi, won ni awon obi omobinrin naa ni Segun wa wa sile.

Won ni nigba tomo naa so pea won obi oun ti loo si soosi, se ni won lo fipa mu omo naa to si ko ibasun fun un, nitori ki omo naa le jajabo, se ni won lo ge je kaakiri ara sibe naa Segun si se nnkan to fee se fun.

Loju ese ti won lo ti sise ibi naa ni won lo ti sa lo ki awon olopaa to rii mu ni agbegbe Mapara Makogi ni Ibafo bakan naa

Nigba ti Segun jewo fawon olopaa, O ni looto loun huwa naa sugbon oun ko le so pe pato nnkan bayii lo sun oun debe, o ni ise esu ni.

O ni o ya oun lenu pe oun le se iru nnkan bee fun omo to n pe oun ni buoda tawon tun jo je ore molebi.

Komisanna fawon olopaa nipinle Ogun, Bashir Makama, ti pase pe ki won gbe afurasi naa loo si eka to n gbejo awon to n lo omo nilikulo, ki won sib ere iwadii laifale.

1 comment:

  1. For sure I love this magazine may God continue to bless the editors

    ReplyDelete

Pages