Ki i se tuntun mo pe agbasere onitiata nii Fasasi Olabinke topo awon ololufe e mo si laye Dagunro laye laaaro kutu ana an niluu Eko, sugbon se ni ekun pe ekun ranse nirole ojo naa nigba ti won fee sinku akoni naa.
Eto isinku e
to waye nilana musulumi niluu Osogbo lopo awon osere ti peju pese lati seye
ikeyin fun agba osere tiku paju e de, gbogbo bi won se wa ekun lawon osere to
sun mo okunrin naa sun, to si n se won bi ala
Sugbon opo
won to ti gbo pe okunrin naa ti wa ninu aisan olojo pipe ti won ti na owo nla
lee lori ti won ko ri ona abayo to fi ku ni won so pe okunrin naa loo sin mi
ni.
Ni nnkan bi
ose meloo kan seyin lawon eeyan n ki osere naa ku ayeye ojoobi aadorin odun to
pe laye tawon kan si n baa dupe, gbogbo ero won ni pe ti ara okunrin naa ba ya daadaa
won yoo sojoobi naa ni alarinrin.
Odu ni
Dagunro lawujo awon osere ki i saimo oloko, opo awon ere isembaye to n gbe asa
Yoruba yo lo saaba maa n gbe jade.
No comments:
Post a Comment