Ko seni
to gbo nnkan ti omobinrin omo Nigeria ti
afesona e, Lawrence, lu lalubami lo ku die ki won segbeyawo ti won ko so pe
okan lara Ruth abokoku ti Bibeli so nipa e ni.
Ohun
taa gbo ni bii kiku, bi yiye ni afesona okunrin e luu, eni ti ko ba si tete mo,
won yoo ro pe obinrin naa idije ese kikan ni, ni won luu toju fi wu.
Sugbon
iroyin fi ye wa pe Omobinrin naa ko loo ko ija debi pe yoo dije fun ese kikan,
oko afesona e lo luu nilukulu to fi ko ija ese kikan.
Gbogbo
oju e lo wuu gan-an, ki e si maa wo inu osu kejo odun yii ni won ti dajo sona
lati se igbeyawo alarinrin, tawon ebi oko ati tiyawo ti loo mu aso ti won fee
lo.
Awon
kan tie so pe won ro pe ijamba moto lo se obinrin naa, won ni igba akoko ko
ree, ti okunrin yii yoo ti maa lu afesona e ni alubami, ti won yoo sit un fi
kinni pari e to dowo asale.
Won ni
nnkan ti Omobinrin naa maa bo oko e, ki i
fee kawon eeyan mo nnkan to sele, ariwo ti won lo maa n pa ni pe nibo loun tun
ti fee bere, oun si nifee.
Ariwo
oun si nifee yii ni won lo si n pariwo, bo se n je irora to, bo tile je pe Lawrence ti sa lo sugbon
gbogbo ibi to ba lo, awon ajafetoo lawon yoo ri mu.
No comments:
Post a Comment