Owo awon osise alabo
So Safe Corps ti awon ore meji kan, Olakunle Korede ati Gbenga Ojo lori esun pe
won ji moto gbe.
Gege bi a se gbo,
laaaro kutu, oni in, ojo ketadinlogbon, osu lowo te awon eeyan naa ni Idi-
Iroko, nipinle Ogun.
Ohun taa gbo ni pe
awon osise alaabo So Safe Corps yii ni gba moto yii lowo awon adigunjale naa
lakookk ti won n gbe sa lo.
Moto korola alawo pupa
ti nomba e je AKD 465.FQ, ti nomba engini e si je 19794211ZZ to je ti Ogbeni Olumoye Femi, to n gbe ni
ojule kokanlelogota,Agboyi. Ketu Alapere, niluu Eko, ni won so pe awon
adigunjale naa gba loju ibon.
Bowo si se te won ni
won ti so pe kawon osise alabo naa se awon pele, awon yoo jewoo boro se je. Ise
dereba ni won so pe Kunle n se ni Lusada, Ado- Odo
Nigba ti won jewoo pe
looto ole lawon, loju ese lawon osise So
Safe Corps fa awon eeyan naa pelu moto ti won gba lowo won fawon olopaa ni Idi
Iroko.
No comments:
Post a Comment