Oga
agba patapata fun ileese fijilnate iyen Vigilante Group of Nigeria,VGN, Usman Mohammed Jahun, ti so pe ipa tawon
fijilante n ko lawujo si dara ju tawon alabo mii in lo, nitori pe awon ni won sunmo
araalu ju ati pe awon yoo fowosowopo pelu ileese alabo mii in lorileede yii.
Ofiisi
won niluu Abuja ni okunrin naa ti soro yii lakooko to n ba oniroyin soro lori
eto abo paapaa ipa tawon fijilante Naijiria ko lati pese abo.
Okunrin
naa tun lo anfaani naa lati tan imloe lori iyato to wa laarin alaabo agbegbe ati
tawon olopaa lawujo. O ni alaabo agbegbe lo nii se pelu bawon awujo se le kopa
nipa gbigbogun ti iwa ibaje.
O
ni ise awon to n gbe ninu agbegbe lati sise lori abo agbegbe won,It is the
community that will drive their own issues of the security, they will tell the
world this I awon nnkan to n sele nibe, eyi lo ni won yoo fi to awon olopaa
leti tawon yoo si sise nipa e.
O
tun so siwaju pe ki i se awon olopaa ni yoo so fun won nnkan ti won yoo se,
awon ara agbegbe ni yoo so fun won nnkan ti won n fe.
O
wa so pe fijilante lo je gege bi alarina laarin awon araalu atawon olopaa, o lawon
ti wa nibe tawon sise takuntakun, tawon si tun ta awon alabo min in lolobo.Opo
igba lawon ti mu odaran tawon ti fa le awon olopaa lowo.
Bee
lo so pe aare Mohammedu Buhari ti setan lati fowo si abo iwadii lori alaabo agbegbe, o ni nnkan
tawon kan n duro de bayii ni awon igbimo ti aare gbe kale ki won jade lati so
erongba won nipa aabo agbegbe lorileede yii.
O ni gbogbo ipinle ati ijoba ibile lorileede
yii lawon wa tawon ti n sise, bee lo tun salaye pe ko si iyapa kankan ninu egbe
fijilante sugbon nnkan to n sele laarin won ni ede aiyede nipa ona ti won n gba
sise.
O
wa gba gbogbo awon ti won ni ikunsinu lati gbagbe nnkan to n sele, o ni odo
enikan soso tawon alase n lo lodo awon.
No comments:
Post a Comment