Gege bi leta ti ilu
mon on ka agbaboolu naa fi ranse si Dapo Abiodun lo ti fi idunnu e han lori
bawon eeyan to n gbe nipinle Ogun, se fibo won gbe okunrin naa wole.
Ninu atejade ti Remmy
Hassan, to je Agbenuso fun Dapo Abiodun fi sita lo ti ni Aare Liberia ti
gboriyin fun aseyori ti okunrin naa se fun ipinnu e lati fi igba ati akoko e sile
lati gbe ohun rere se fawon eeyan ipinle e, nipa sinsin won.
Bee lokunrin naa wa gbadura aseyori fun gomina tuntun naa
lakoko ijoba e. Nigba to n fesi lori ikinni ku oriire naa, Dapo Abiodun ni
gbigba leta ikinni ku oriire lati odo Aare Liberia, George Weah atawon eeyan
pataki kaakiri agbaye foun lokabale
Pe ifowosowopo yoo wa
laarin oun atawon omo ipinle Ogun ati nibi gbogbo, o wa loun setan lati dojuko
isejoba rere fawon eeyan oun.
No comments:
Post a Comment