Beeyan ba se
n daadaa, to n se ohun iwuri, o ye ki won maa pon iru eni bee le, ko fi le je
ohun iwuri fun un lati maa te siwaju. Iru e lo waye lojo Sannde, to koja nigba
tawon Oba Alade wa sibi ayeye ojoobi, gbajumo oniroyin obinrin nni, Folasade
Obadele
Ayeye naa to
waye ni ooteli kan to wa ni New Oko Oba, Abule Egba lawon oba, oloselu, awon
oga olopaa to fi mo awon akegbe e nidi ise oniroyin ti wa ba sajoyo pe o tun le
odun kan lojo naa.
Oba orile
tiluu Agege ati Ololo tiluu ijofin ni won sapejuwe omo olojoobi naa gege bi
oniwarele, to si ni akinkanju nidii ise to n se, won lo tun feran asa ati ise,
idi niyii ti ki i fi jinna sawon oba alaye, won wa gbadura fun un pe yoo se opo
odun laye.
Bee lawon
agba oloselu atawon ore e naa sapejuwe iru eeyan to je. Eyi ni die lara foto
ayeye naa.
No comments:
Post a Comment