Apapo egbe oselu ipinle Ogun ni ki won da iwe esun APM nu bi omi isanwo. - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Friday 10 May 2019

Apapo egbe oselu ipinle Ogun ni ki won da iwe esun APM nu bi omi isanwo.
Apapo egbe oselu nipinle Ogun ti so fun aare kootu ko te mi-lorun niluu Abuja lati da igbese leta esun ehonu tegbe oselu Allied People's Movement (APM) nu bi omi isanwo, nitori ko lese nile.

Gege bi atejade ti won fi sita ni won ti sapejuwe igbese tegbe oselu APM gbe yii gege bi eyi ti won fee maa pase fun ofin, to si nii se pelu oselu ninu.

Ninu iwe tawon alaga egbe oselu mokanla fowo si ti won ko si Adajo Zainab Bulkachuwa to je aare kootu ko- te mi-lorun ti won pe akole e ni iwe ehonu si egbe oselu Allied Peoples Movement ko si oluwa mi" eyi ti won ko lojo keji, osu karun un, odun yii ni won tun ka si bigba ti won fee maa sin ile baba lona ti ko bojumu.

Won nigba tawon ye awon esun tegbe oselu APM ka sile eyi ti won fi sowo sawon oniroyin kaakiri, awon rii pe ko si nnkan gidi dabi alara nibe ti won fi so pe won kuna nibi ibo to waye

Won tun so pe ohun to han daju gbangba ni pe gomina ipinle tabi igbakeji aare ko lagbara labe ofin lati yan adajo gege bo se wa ninu ofin ajo eto idajo iyen NJC.

Bee legbe apapo oselu nipinle naa tun salaye bi won se satunto igbimo to n gbejo naa ki i se nipinle Ogun nikan kaakiri awon apa ibi kan lorileede yii  ni. Won ni ka ni bawon APM se n se lawon egbe oselu yooku naa nipinle Ogun kowe esun, bawo lo se fee ri.

Won ni pelu nnkan tegbe oselu APM se fihan daju gbangba lori bi won se leni to n sagbateru egbe naa nipinle Ogun gbe bilionu kan naira sile lati le maa fi pase fawon onidajo.

Won tun so pe iru nnkan to sele nipinle Ogun fun ti ibo gomina ko sele rii nibi tawon oludije gomina yooku ti gba fun Olorun, ti won loo ki Dapo Abiodun to wole nile e, ti won si gba lati sise po, ki lo wa tun ku, leyin eleyii.

Egbe naa war o aare naa lati ma se ri ti APM ro rara nitori awon nigbagbo ninu igbimo tuntun ti won sese gbe kale lati gbo ejo gomina.


No comments:

Post a Comment

Pages