Gbogbo awon to ri bi gbajumo osere tiata nni, Eniola Badmos, se n ya foto kaakiri ogba ibi ti gomina tuntun nipinle Ogun, Omooba Dapo Abiodun ti n sagbekale igbimo ti yoo sise lori sise ijoba tuntun ati oro aje, ni won beere lowo ara won pe se foto lo wa ya lojo naa.
Nibi eto naa
to waye niluu Ogere lo je pe gbogbo nnkan to n se lo ni ki onifoto ti won jo wa
maa ya. Bo tlle je pe osere naa wa lara awon omo igbimo ti yoo sise po pelu
awon ti won yan naa sibe o fee dabi pe foto gan-an wa lara nnkan to wa se lojo
naa.
Nigba ti aye
yoo wa gba osere naa daadaa ni akoko ti won fun won ni isinmi ranpe se loun ati
onifoto e jo n rin kaakiri inu ogba naa, to ni ki onitohun maa ya oun, to ba
gbe ese kan bayii, a ni ko ya oun ati beebee lo.
Idi niyi
tawon to ru Wulebantu fi so pe boya igbimo awon to wa ya foto ni Dapo Abiodun
fi si.
No comments:
Post a Comment