Egbe awon osere nipinle Ogun ti fi atileyin won han si oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APM, Onarebu Abdulkabir Akinlade lati dibo won fun un ninu ibo to n bo lojo Satide ose yii.
Nibi ipade
tawon osere tiata, olorin atawon sorosoro se pelu okunrin naa ni gbongan
Cultural Centre, Kuto, niluu Abeokuta ni won ti muu da loju pea won yoo rii pea
won polongo fawon araalu lati dibo fun ati awon ko nibo feeyan meji ju oun lo.
Lara awon
osere to wa nibi ipade naa lati ri awon TAMPAN, ATNP tawon je onitiata , awon
olorin fuji, juju naa ko gbeyin ti won si fokan okunrin naa bale pe didun ni
osan yoo so.
Oludije
gomina naa ti wa mu da gbogbo awon osere loju pe gbogbo nnkan to ba wa nikawo
oun loun yoo se fun won ati pe oun yoo rii pe ifowosowopo to wa pelu won ati
Gomina Amosun fa seyin toun ba dori ipo.
O ni oun yoo
sa agbara lati rii pe itesiwaju tubo deba awon osere nipinle Ogun.
No comments:
Post a comment