Iwe iroyin Yoruba tuntun kan ti jade o, ASEJERE ni won n pe e - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 26 February 2019

Iwe iroyin Yoruba tuntun kan ti jade o, ASEJERE ni won n pe e


 
Lati le mu itesiwaju ba oro aje awon omo Yoruba ati ki asa ati ese wa maa ba parun, iwe iroyin YORUBA  tuntun kan ti jade bayii si igboro, iwe iroyin Asejere ni won n pe e, odo awon to maa n ta iwe iroyin iyen fendo le o si ti maa ri ra.

Gege bi a se gbo, iwe iroyin yii ni yoo je akoko ti yoo maa so nipa bi nnkan se n loo si nipa okoowo, oro aje, ohun to n lo lagbo osere to lokiki nidi ise tiata ati orin, ti won tun je ojulowo onisowo.

Awon gbajumo onisowo, ti won ni okoowo-nla yoo tun maa lo anfaani lati gbe oro aje won jade nipa bi won se bere ati ibi ti won ba okoowo won de ati ona ti won le gba se asejere nipa ise naa..

Bee la tun gbo pe gbogbo awon araalu lo tun wa fun latile fi tun ni imo kikun nipa ede Yoruba ati pe ilosiwaju nla ni yoo mu ba ile Yoruba paapaa lori igbelaruge oro aje atawon ise abinibi ile omo Oduduwa ti ko gbodo dawati lawujo wa.


Won ni osoosu niwe iroyin yii naa yoo maa jade lati akoko yii lo Eyi to si ti wa nita bayii tawon araalu ti n tu yaya sita lati ra.

No comments:

Post a Comment

Pages