![]() |
Dapo Abiodun |
Ninu atejade kan ti Remmy Hassan to
je agbenuso fun okunrin naa fi sita lojo Aiku, Sannde, lo ti ba awon omo ipinle
naa yo pe ayajo ayeye odun tun soju won.
O ni bo tile je pe ipinle naa to ba
bo tipe pelu awon isakoso ti won ti se atawon to si n se lowo bayi ni won ti sa
ipa won lati mu idagbasoke ba ipinle naa latigba ti won ti daa sile.
Bee lo tun gboriyin fawon asaaju omo
bibi ipinle atawon gomina ti won ti je fawon ipa tawon naa ti kofun ipo agba tipinle naa wa.O ni eyi
tun mu idaniloju wa pe ipinle Ogun yoo tubo gberu sii lojo iwaju.
Agbenuso naa tun so pelu pe ipinle
Ogun pe omo odun metalelogoji, o so pe a ti tiraka lati mu ala wa se nipa bawon
babanla was se fee ki ipinle naa ko ri. O ni bee loun naa gbero ninu ala oun
lati rii pe ipinle naa dun un wo loju just bo se wa lo toun si mo pe Olorun yoo
mu ala oun se.
O wa to awon elegbejegbe ati
olokoowo lati jo sise po ki ipinle naa le ri bawon se n fee ni rere
No comments:
Post a Comment