Ademola Ogunbanjo oludije gomina fegbe oselu ANN fakoyo nibi ariyanjiyan BBC Yoruba - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Saturday 9 February 2019

Ademola Ogunbanjo oludije gomina fegbe oselu ANN fakoyo nibi ariyanjiyan BBC Yoruba


Ademola Ogunbanjo
 
Opo awon to wa sibi ariyanjiyan laarin awon oludije gomina fun ibo gomina ti yoo waye ninu osu keta, eyi ti BBC Yoruba sagbekale e to won pe ni gbagede oro bi won kan sara si Ademola Ogunbanjo to je okan lara won pe o fakoyo.

Nibi eto naa to waye ni gbongan OOPL to wa niluu Abeokuta lojo Eti, Furaide, ni won so pe loooto ni Olorun fi opolo jinki oludije gomina labe egbe oselu ANN naa.

Lara awon oludije gomina yooku ti won tun wa nibe lojo naa ni Gboyega Nasir tegbe oselu ADC, Abdulkabir Akinlade tegbe oselu APM ati Rotimi Paseda tegbe oselu SDP. Awon oludije yooku bi Buruji Kashamu tegbe PDP, Dapo Abiodun tegbe APC ati Dimeji Bankole tegbe ADP ni won ko yoju, ti won ko si ranse, awon eeyan bi boya ede Yoruba ko dun lenu won ni.

Ohun tawon eeyan fi n so pe Ogunbanjo tawon egbe e yooku lo ni ogbon agbejale to fi n gbe awon ibeeere to won n beeere lowo e kale.

Ati pe beeyan ko ba sunmo okunrin naa ko nii mo pe o sese wonu oselu ni.  Won ni bawon omo egbe ba le satileyin fun un daadaa lori ipolongo o se e se ki okunrin naa rowo mu.

Won niru awon olopolo pipe tipinle Ogun n fee ti won le tuko ipinle naa daadaa ni Ogunbanjo, nitori ogbon ati se ilu lona to dara wa lopolopo e, won wa fadura ran an lowo lati saseyori.
https://ssl.gstatic.com/ui/v1/icons/mail/no_photo.pngNo comments:

Post a Comment

Pages