Awon egbe oselu mefa
kan nipinle Ogun, ti so pe awon ko fowo si oro kan ti Abayomi Oluwafemi Arabanbi
gbe
e jade loruko apapo egbe oselu nipinle Ogun iyen IPAC nibi ti won ti fun Dapo
Abiodun, oludije gomina labe egbe oselu APC ni gbedeke.
Ninu atejade tawon egbe
oselu mefa naa,Green Party of Nigeria, Unity Party of Nigeria,Democratic
People's Party,
Nigeria Interest Party,
Ogun Labour Party ati National Interest Party (NPI) gbe jade ni won ti so pe
apo ara Arabanbi lo so oro naa si, ki i se ajomo awon.
Won ni gege bi apapo
egbe naa, won ni gbedeke ti won fun Dapo Abiodun, oludije gomina labe egbe
oselu APC kawon araalu ma ka si, nitori ko sibi tawon ti jo se ipade tawon fi
so iru e jade, won ni adase funra e lo foro naa se.
Won tun soo di mimo pe
kawon eeyan ma se gbagbe pe Arabambi ki i se ojulowo alaga egbe oselu Labour
nipinle Ogun, won ni alaga igun kan ni ati pe ajo EFCC ti n se iwadii e lowo,
lori awon esun jibiti ti won fi kan an.
Won wa kesi awon
araalu ati oludije gomina labe egbe oselu APC , Dapo Abiodun, lati ma se ka oro
e kun, won ni gbogbo oro e atawon ti won jo n rin lo kun fun iro, ti ko ye
kawon eeyan maa gbagbo.
Won ni
niwongba ti oro naa ti wa ni kootu ki lo de to n gbon bi ewe jobele ti ko je ki
ofin sise funra e. won wa ni okunrin naa ki i se eni to ye ki won
No comments:
Post a Comment