Lati le je kawon eeyan
ipinle Ogun mo pe agbara Olorun si wa sibe nipinle Ogun,Wolii Omooba Olatunde Rotimi
Paseda to je oludije gomina fun ibo gomina fodun 2019 ti sagbekale isoji Sannde
meta lawon ekun meta ti won pin ipinle naa si.
Isoji naa ti won ni
ileese ijihinrere lagbaye Paseda peluu ajosepo awon to wa niwaju Olorun
sagbekale e ti won pe akole e ni isoji ireti yii ni yoo bere lojo Aiku
Sannde otunla tii se ojo keta osu
ni Faith Chapel
Christian Center, Isiba, Abeokuta express way, Sango-Ota.
Nigba ti ti Ogun
Central to je eleekeji e yoo waye lojo kewaa osu ni The Blood of Jesus
Chapel, legbe INEC Annex office, Ijeun-Titun, Iyana Mortuary,
Abeokuta.
Pabanbari e ni
elekeeta ti won yoi se lojo Aiku Sannde bakan naa ni ojo ketadinlogun osu
ni Glorious charismatic Church,10 Eka street, bonojo, Ijebu-Ode, Ogun
State.
Aago meta osan ni awon
isoji yii yoo bere lawon ojo naa bee naa ni won yoo tun fi adura ran ojo iwaju
ipinle Ogun ati orile ede yii lowo lojo naa.
Nigba ti Ojise
Olorun,Omooba Rotimi Paseda yoo foro Olorun bo awon eeyan lakoko ti isoji naa
ba n loo lowo.
.
No comments:
Post a Comment